| WHATSAPP GROUP | TELEGRAM CHANNEL |
|---|
| SUBSCRIBER TO YOUTUBE CHANNEL |
|---|

Another lovely brand new gospel music from Sola Allyson – Ijoba Re De.
Nigerian award winning Christian Gospel music minister, music singer, songwriter and worship leader, Sola Allyson has released another powerful brand new gospel music which she titled “Ijoba Re De”. And it’s right available here on Gospelhome.com.ng for your free and fast download!
Check Out The Full Lyrics Below;
Ijoba Re de, ase Re bereAgbara wa, o ba sori miIjoba Re de, ase Re bereAgbara wa, o ba sori miIjoba Re de, ase Re bereAgbara wa, o ba sori miIjoba Re de, ase Re bereAgbara wa, o ba sori miIjoba Re de, ase Re bereAgbara wa, o ba sori miIjoba Re de, ase Re bereAgbara wa, o ba sori miIjoba Re de, ase Re bereAgbara wa, o ba sori mi
Okunkun ka, Imole deIranwo de, gbogbo ise n kun mi lowoIse mo wa se, ise Imole, ma a s’ aseyeMa a rin arinto, ma a rin arinyeAgbara wa, o ba sori mi
Okunkun ka, Imole deIranwo de, gbogbo ise n kun mi lowoOkunkun ka, Imole deIranwo de, gbogbo ise n kun mi lowoIse mo wa se, ise Imole, ma a s’ aseyeMa a rin arinto, ma a rin arinyeAgbara wa, o ba sori mi
Mo f’ebun sola oBee naa lo riMo f’ebun mi fogo fun Oluwa t’O l’ebun miBee naa lo riIjoba Re de oOwo yida lori iseda miAse Re lat’ orun bere, bee naa lo riOwo yida lori iseda miIsodotun de ba mi ni ‘rin ajo miBee naa lo riMy men shall not be few, iranwo lat’ origun mereerin agbaye temi niBee naa lo riAwon t’o ma gbe mi, t’ ‘on ma sugba ohun mo gbe ka ‘ri, won wa s’ona miBee naa lo riIjoba Re de oOwo yida lori iseda miSi ti aanu, si ti iranwo, si ti iserere, bee naa niOwo yida lori iseda miIranwo ti mi o ri ri, ma a ri lona gbogbo, bee naa niBee naa lo riAye mi a bu ola fun O, Eni ti O ni ebun mi, bee naa niBee naa lo riBee naa lo ri o, pelu ase Baba miOwo yida lori iseda miMo ti di omoApeere omo wa lara miOwo yida lori iseda mi
Agbara wa, O ba s’ori mi
| GospelHome Don't Claim the Ownership of the songs and media on this page, They are shared for gospel promotion purposes only. All rights belong to the respective artists and labels. If you are the rights holder and wish content removed, please read our DMCA & Copyright Policy or Contact Us For Copywriting Take DownContact Us |
|---|
DOWNLOAD MP3
Download Below!
What do you think about this song?
We want to hear from you all.
Drop your comments
